Deutarónómì 31:3 BMY

3 Olúwa Ọlọ́run rẹ fúnra rẹ̀ ni yóò rékọjá fún ọ. Yóò pa àwọn orílẹ̀ èdè yìí run níwájú ù rẹ, ìwọ yóò sì mú ìní ilẹ̀ wọn, Jósúà náà yóò rékọjá fún ọ, bí Olúwa ti sọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 31

Wo Deutarónómì 31:3 ni o tọ