Deutarónómì 32:10 BMY

10 Ní ihà ni ó ti rí i,ní ihà níbi tí ẹranko kò sí.Ó yíká, ó sì tọ́jú u rẹ̀,ó pa á mọ́ bí ẹyin ojú u rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:10 ni o tọ