Deutarónómì 32:13 BMY

13 Ó mú gun ibi gíga ayéó sì fi èṣo oko bọ́ ọ.Ó sì jẹ́ kí ó mú oyin láti inú àpáta wá,àti òróró láti inú akọ òkúta wá,

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:13 ni o tọ