Deutarónómì 32:15 BMY

15 Jéṣúrúnì sanra tán ó sì tàpá;ìwọ ṣanra tán, ìwọ ki tan, ọ̀rá sì bò ọ́ tán.O kọ Ọlọ́run tí ó dá ọo sì kọ àpáta ìgbàlà rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:15 ni o tọ