Deutarónómì 32:17 BMY

17 Wọ́n rúbọ sí iwin búburú, tí kì í ṣe Ọlọ́run,ọlọ́run tí wọn kò mọ̀ rí,ọlọ́run tí ó sẹ̀sẹ̀ farahàn láìpẹ́,ọlọ́run tí àwọn baba yín kò bẹ̀rù.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:17 ni o tọ