Deutarónómì 32:30 BMY

30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún,tàbí tí ẹni méjì sì lè lé ẹgbàaàrún sá,bí kò ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,bí kò ṣe pé Olúwa wọn ti fi wọ́n tọrẹ?

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:30 ni o tọ