Deutarónómì 32:51 BMY

51 Ìdí ni pé ẹ̀yin méjèèjì ṣẹ̀ sí mi láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ibi omi Móríbà Kádésì ní ihà Ṣínì àti nítorí ẹ̀yin kò yà mí sí mímọ́ láàrin àwọn ọmọ Isírẹ́lì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:51 ni o tọ