Deutarónómì 33:2 BMY

2 Ó sì wí pé:“Olúwa ti Sínáì wá,ó sì yọ sí wọn láti Ṣéírì wáó sì tàn án jáde láti òkè Páránì wá.Ó ti ọ̀dọ̀ ẹgbẹgbàarùn ún àwọn mímọ́ wáláti ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ ni òfin kan amúbíiná ti jáde fún wọn wá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 33

Wo Deutarónómì 33:2 ni o tọ