Deutarónómì 34:7 BMY

7 Mósè jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù.

Ka pipe ipin Deutarónómì 34

Wo Deutarónómì 34:7 ni o tọ