Deutarónómì 4:1 BMY

1 Gbọ́ Ísírẹ́lì, gbọ́ òfin àti ìlànà tí èmi yóò kọ́ ọ yín. Ẹ tẹ̀lé wọn kí ẹ ba à lè yè, kí ẹ ba à lè lọ láti gba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run àwọn baba yín yóò fi fún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:1 ni o tọ