Deutarónómì 4:15 BMY

15 Ẹ kíyèsára gidigidi, torí pé, ẹ kò rí ìrísí ohunkóhun ní ọjọ́ tí Olúwa bá yín sọ̀rọ̀ ní Hórébù láti àárin iná wá. Torí náà ẹ sọ́ra yín gidigidi,

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:15 ni o tọ