Deutarónómì 4:20 BMY

20 Olúwa Ọlọ́run yín sì ti mú ẹ̀yin jáde kúrò nínú iná ìléru ńlá, àní ní Ị́jíbítì, láti lè jẹ́ ènìyàn ìní i rẹ̀, bí ẹ̀yin ti jẹ́ báyìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:20 ni o tọ