Deutarónómì 4:30 BMY

30 Bí ẹ bá wà nínú wàhálà, bí gbogbo nǹkan wọ̀nyí bá ṣẹlẹ̀ sí yín, láìpẹ́ ẹ ó tún padà tọ Olúwa Ọlọ́run yín wá, ẹ ó sì gbọ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:30 ni o tọ