Deutarónómì 4:32 BMY

32 Ẹ bèèrè báyìí nípa ti àwọn ọjọ́ ìgbàanì ṣáájú kí a tó bí i yín, láti ìgbà tí Ọlọ́run ti dá ènìyàn sórí ilẹ̀ ayé. Ẹ bèèrè láti igun ọ̀run kan sí èkejì. Ǹjẹ́ irú nǹkan olókìkì báyìí: ti ṣẹlẹ̀ rí? Ǹjẹ́ a ti gbọ́ irú u rẹ̀ rí?

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:32 ni o tọ