Deutarónómì 4:49 BMY

49 Àti gbogbo aginjù ní ìlà oòrùn Jọ́dánì títí dé òkun aginjù (òkun iyọ̀) ní ìṣàlẹ̀ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:49 ni o tọ