Deutarónómì 4:8 BMY

8 Orílẹ̀ èdè wo ló tún le lókìkí láti ní àwọn ìlànà òdodo, àti òfin gẹ́gẹ́ bí àwọn òfin wọ̀nyí tí mo ń gbé kalẹ̀ fún un yín lónìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 4

Wo Deutarónómì 4:8 ni o tọ