Deutarónómì 6:22 BMY

22 Lójú wa ni Olúwa tí ṣe iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu: tí ó lágbára tí ó sì ba ni lẹ́rù: lórí Éjíbítì àti Fáráò, àti gbogbo ènìyàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 6

Wo Deutarónómì 6:22 ni o tọ