Deutarónómì 6:24 BMY

24 Olúwa pàṣẹ fún wa láti ṣe ìgbọ́ran sí gbogbo ìlànà wọ̀nyí, làti bẹ̀rù Olúwa Ọlọ́run wa, kí ó báà lè má a dára fún wa nígbà gbogbo, kí a sì lè wà láyé, bí a se wà títí di òní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 6

Wo Deutarónómì 6:24 ni o tọ