Deutarónómì 7:21 BMY

21 Ẹ má gbọ̀n jìnnìjìnnì torí wọn, torí pé Olúwa Ọlọ́run yín tí ó wà láàrin yín, Ọlọ́run alágbára ni, àti Ọlọ́run tí ó tóbi lọ́pọ̀lọpọ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:21 ni o tọ