Deutarónómì 7:4 BMY

4 torí pé wọ́n á yí àwọn ọmọ yín padà kúrò lẹ́yìn mi, láti jẹ́ kí wọn máa sin òrìṣà, ìbínú Olúwa yóò sì wá sórí yín, yóò sì run yín kíákíá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 7

Wo Deutarónómì 7:4 ni o tọ