Deutarónómì 8:11 BMY

11 Ẹ ṣọ́ra kí ẹ má gbàgbé Olúwa Ọlọ́run yín, nípa kíkùnà láti pa àṣẹ rẹ̀, àwọn òfin rẹ̀, àti àwọn ìlànà rẹ̀ tí mo ń fún un yín lónìí mọ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:11 ni o tọ