Deutarónómì 8:15 BMY

15 Òun ni ó mú un yín la ihà ńlá já, ilẹ̀ tí kò sí omi tí ó sì kún fún òùngbẹ, pẹ̀lú àwọn ejò olóró ńláńlá àti àkéekèe. Ó mú omi jáde fún un yín láti inú àpáta.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:15 ni o tọ