Deutarónómì 8:9 BMY

9 Ilẹ̀ tí oúnjẹ kò ti wọ́n, kò sí ohun tí ẹ̀yin yóò ṣe aláìní, ilẹ̀ tí irin ti pọ̀ bí òkúta, ẹ̀yin sì lè wa idẹ jáde láti inú òkè rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 8

Wo Deutarónómì 8:9 ni o tọ