Deutarónómì 9:14 BMY

14 Fi mí sílẹ̀, jẹ́ kí n run wọ́n, kí n sì pa orúkọ wọn rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run. Èmi yóò sì sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè tí ó lágbára tí ó sì pọ̀ jù wọ́n lọ.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:14 ni o tọ