Deutarónómì 9:29 BMY

29 Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn rẹ ni wọ́n, ogún rẹ tí o ti fi ọwọ́ agbára rẹ àti nínà ọwọ́ rẹ mú jáde.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:29 ni o tọ