Deutarónómì 9:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n kí ó yé yín pé kì í ṣe nítorí òdodo yín ni Olúwa Ọlọ́run yín fi ń fún un yín ní ilẹ̀ rere náà, láti ní, nítorí pé alágídí ènìyàn ni ẹ jẹ́.

Ka pipe ipin Deutarónómì 9

Wo Deutarónómì 9:6 ni o tọ