Ísíkẹ́lì 11:19 BMY

19 N ó fún wọn ní ọ̀kan kan; èmi yóò sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn; N ó mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn, n ó sì fún wọn ní ọkàn tó rọ̀ bí ara ẹran.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:19 ni o tọ