Ísíkẹ́lì 11:20 BMY

20 Kí wọn le tẹ̀lé àṣẹ mi, kí wọn sì le pa òfin mi mọ́. Wọ́n yóò jẹ́ ènìyàn mi, Èmi náà yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:20 ni o tọ