Ísíkẹ́lì 11:21 BMY

21 Ṣùgbọ́n fún àwọn tí wọ́n ń fi gbogbo ọkàn wọn sin àwọn àwòrán ìríra àti àwọn òrìṣà, Èmi yóò mú ẹ̀san ohun tí wọ́n ṣe wá sórí wọn bẹ́ẹ̀ ni Olúwa Ọlọ́run wí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 11

Wo Ísíkẹ́lì 11:21 ni o tọ