Ísíkẹ́lì 12:16 BMY

16 Ṣùgbọ́n n ó ṣẹ́ díẹ̀ kù lára wọn, lọ́wọ́ idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn, kí wọn le jẹ́wọ́ gbogbo ìṣe ìríra wọn láàrin àwọn orílẹ̀ èdè yìí. Nígbà náà ni wọn ó mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:16 ni o tọ