15 “Wọn ó sì mọ̀ pé èmi ni Olúwa láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, tí mo bá tú wọn ká láàrin àwọn orílẹ̀ èdè, tí mo sì fọ́n wọn ká sí ilẹ̀ káàkiri.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12
Wo Ísíkẹ́lì 12:15 ni o tọ