Ísíkẹ́lì 12:27 BMY

27 “Ọmọ ènìyàn, ilé Ísírẹ́lì ń wí pé, ‘Ìran ọjọ́ pípẹ́ ni ó rí, ó sì sọtẹ́lẹ̀ nípa àsìkò tó jìnnà réré.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:27 ni o tọ