Ísíkẹ́lì 12:28 BMY

28 “Nítorí náà sọ fún wọn, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Kò sí ọ̀kan nínú ọ̀rọ̀ mi tí yóò sún ṣíwájú mọ́; ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí mo bá sọ yóò ṣẹ.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:28 ni o tọ