Ísíkẹ́lì 13:11 BMY

11 nítorí náà, sọ fún àwọn tí ń fi amọ̀ àìpò rẹ̀ ẹ àti àwọn tó fi ẹfun kùn ún pé, odi náà yóò wó, ìkún omi òjò yóò dé, N ó sì rán òkúta yìnyín sọ̀kalẹ̀, ìjì líle yóò ya á lulẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:11 ni o tọ