12 Nígbà tí odi náà bá sì wó, ǹjẹ́ àwọn ènìyàn wọn ò ní bi yín pé, “Rírẹ́ tí ẹ rẹ́ ẹ dà, ibo sì ni ẹfun tí ẹ fi kùn ún wà?”
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13
Wo Ísíkẹ́lì 13:12 ni o tọ