Ísíkẹ́lì 14:8 BMY

8 N ó lodi si írú ọkùnrin bẹ́ẹ̀ lọ́nà òdì, n ó sì sọ ọ́ di àánú àti òwe. Èmi yóò sì gé e kúrò láàrin àwọn ènìyàn mi. Nígbà náà, ẹ ó mọ̀ pé èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:8 ni o tọ