Ísíkẹ́lì 14:9 BMY

9 “ ‘Bí wọ́n bá sì tan wòlíì náà láti sọtẹ́lẹ̀, Èmi Olúwa ló tan wòlíì náà, Èmi yóò nawọ́ sí i, èmi yóò sì pa á run kúrò láàrin àwọn ènìyàn mi Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:9 ni o tọ