Ísíkẹ́lì 16:15 BMY

15 “ ‘Ṣùgbọ́n, o gbẹ́kẹ̀lé ẹwà rẹ, o sì di alágbérè nítorí òkìkí rẹ. O sì fọ́n oju rere rẹ káàkiri sórí ẹni yòówù tó ń kọjá lọ, ẹwà rẹ sì di tìrẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:15 ni o tọ