Ísíkẹ́lì 16:16 BMY

16 O mú lára àwọn aṣọ rẹ, láti rán aṣọ aláràbarà fún ibi giga òrìṣà tí o ti ń ṣàgbèrè. Èyí kò yẹ kó rí bẹ́ẹ̀, tàbí kó tilẹ̀ ṣẹlẹ̀ rárá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:16 ni o tọ