Ísíkẹ́lì 16:19 BMY

19 O tún gbé oúnjẹ tí mo fún ọ-ìyẹ̀fún dáradára, òróró àti oyin-fún wọn gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn; ohun tó ṣẹlẹ̀ nìyìí, ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:19 ni o tọ