Ísíkẹ́lì 16:25 BMY

25 Ní gbogbo òpin ojú pópó lo kọ ojúbọ gíga sí tó o sì fi ẹwà rẹ̀ wọlé, o sọ àgbèrè rẹ di púpọ̀ nípa fífi ara rẹ sílẹ̀ fún gbogbo ẹni tó ń kọjá lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:25 ni o tọ