Ísíkẹ́lì 16:26 BMY

26 O ṣe àgbèrè pẹ̀lú ará Éjíbítì tí í ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ aládúgbò rẹ láti mú mi bínú pẹ̀lú ìwà àgbèrè rẹ tó ń pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:26 ni o tọ