Ísíkẹ́lì 17:23 BMY

23 Ní ibi gíga òkè Ísírẹ́lì ni èmi yóò gbìn ín sí; yóò pẹ̀ka, yóò sì so èso yóò wa di igi Kédárì tí ó lọ́lá. Orírsìírísìí ẹyẹ yóò sì fi òjìji abẹ ẹ̀ka rẹ ṣe ibùgbé; wọn yóò ṣe ibùgbé si abẹ́ òjìji ẹ̀ka rẹ̀

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:23 ni o tọ