Ísíkẹ́lì 17:24 BMY

24 Gbogbo igi inú oko yóò mọ̀ pé, Èmi Olúwa ni ó mú igi gíga walẹ̀, tí mo sì mú kúkurú ga sókè, tí mo mu igi tútù gbẹ, tí mo sì mú igi gbígbẹ rúwé.“ ‘Èmi Olúwa ni ó sọ bẹ́ẹ̀, Èmi yóò sì se e.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:24 ni o tọ