Ísíkẹ́lì 17:3 BMY

3 Sọ fún wọn pé, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Idì ńlá kan tó ní apá títóbi àti ìyẹ́ gígùn tó kún fún àwọ̀ orísìírísìí wa si Lẹ́bánónì o sì mu ẹ̀ka igi Kédàrì tó ga jùlọ

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:3 ni o tọ