Ísíkẹ́lì 17:4 BMY

4 O gé ọ̀mùnú orí ẹ̀ka yìí kúrò, o mu un lọ sí ilẹ̀ oníṣòwò, ó sì gbìn ín sí ìlú àwọn ọlọ́jà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:4 ni o tọ