Ísíkẹ́lì 17:5 BMY

5 “ ‘Ó mú lára irúgbìn ilẹ̀ náà, ó gbìn ín sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi, ó gbìn ín bí igi wílóò.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:5 ni o tọ