Ísíkẹ́lì 17:6 BMY

6 Ó dàgbà, ó sì di àjàrà to kúrú ṣùgbọ́n to bolẹ̀. Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ kọjú si i, gbòǹgbò rẹ̀ sì dúró lábẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni o di àjàrà ó sì mu ẹ̀ka àti ewe jáde.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 17

Wo Ísíkẹ́lì 17:6 ni o tọ