Ísíkẹ́lì 19:7 BMY

7 Ó sì wó odi wọn palẹ̀ ó sì sọ àwọ̀n ìlú wọn di ahoro.Ilẹ̀ náà àti àwọn olùgbé ibẹ̀ sì wà ní ìpayà nítorí bíbú ramúramù rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 19

Wo Ísíkẹ́lì 19:7 ni o tọ