Ísíkẹ́lì 20:32 BMY

32 “ ‘Ẹ̀yin wí pé, “Àwa fẹ dàbí àwọn orílẹ̀ èdè yóòkù, bí àwọn ènìyàn ayé, tó ń bọ igi àti òkúta.” Ṣùgbọ́n ohun ti ẹ ni lọ́kàn kò ní ṣẹ rárá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:32 ni o tọ